Ezekiel 13:16
16
Àwọn wòlíì Israẹli tí ń sọtẹ́lẹ̀ sí Jerusalẹmu, tí wọn ríran àlàáfíà sí i nígbà ti kò sì àlàáfíà, báyìí ni
Olúwa
Olódùmarè wí.” ’
Copyright information for
YorBMYO